Angélique Kidjo : Ominira [Music : Lyrics]
Onikaloukou wa n'fè ri ominira
Onikaloukou wa n'fè aseyori
Onikaloukou wa n'fè ri oyaya
Onikaloukou fèlo wa idaji
Mmm ewa ka lo
Ka lo fè wa tchitchè kori ominira
N'tori ominira toro ishè gan
Edahoun gbogbo yin foun ominira
Aaah ominira, foun min l'owo ka man
Lo ominira
Aaah ominira, foun min l'owo ka man
Lo ominira
Owa iya iyé é a, owa iya iyé é a
Owa iya iyé é a
Owa iya iyé é a, owa iya iyé é a
Owa iya iyé é a
Onikaloukou wa n'fè ri ominira
Onikaloukou wa n'fè aséyori
Onikaloukou wa n'fè ri oyaya
Onikaloukou fèlo wa idaji
Ayé wa toro kawa ri ominira
Ayé wa fè dada foun gbogbo èniyan
Ayé sin wa lodo ominira
Mmm ewa ka lo
Aaah ominira, foun min l'owo ka man
Lo ominira
Aaah ominira, foun min l'owo ka man
Lo ominira
Onikaloukou wa n'fè ri ominira
Onikaloukou wa n'fè aséyori
Onikaloukou wa n'fè ri oyaya
Onikaloukou fèlo wa idaji
Ayé wa toro kawa ri ominira
Ayé wa fè dada foun gbogbo èniyan
Ayé sin wa lodo ominira
Mmm ewa ka lo a
Aaah ominira, foun min l'owo ka man
Lo ominira
Aaah ominira, foun min l'owo ka man
Lo ominira
Aaah ominira
Lo, ominira
Aaah ominira
Lo, ominira
Aaah ominira
Lo, ominira
Aaah ominira
Lo, ominira
Aaah ominira
Lo, ominira
Aaah ominira, foun min l'owo ka man
Lo ominira
Aaah ominira, foun min l'owo ka man
Lo ominira